Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 7:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí mo ṣe ń ronú nípa ìwo náà, nígbà náà ni mo rí ìwo mìíràn, tí ó kéré tí ó jáde wá ní àárin wọn; mẹ́ta lára àwọn ìwo ti àkọ́kọ́ sì fà tu níwájú u rẹ̀. Ìwo yìí ní ojú bí i ojú ènìyàn àti ẹnu tí ń sọ̀rọ̀ ìgbéraga.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 7

Wo Dáníẹ́lì 7:8 ni o tọ