Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 7:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Odò iná ń ṣànó ń jáde ní iwájú u rẹ̀Àwọn ẹgbẹ̀rún lọ́ná ẹgbẹ̀rún ń foríbalẹ̀ fún un;Ọ̀nà ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá lọ́nà ẹgbẹ̀rúnmẹ́wàá sì dúró níwájú u rẹ̀.Àwọn onídàájọ́ jókòóa sì sí àwọn ìwé sílẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 7

Wo Dáníẹ́lì 7:10 ni o tọ