Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 7:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lẹ́yìn èyí, nínú ìran mi lóru mo tún rí ẹranko kẹrin, ó dẹ́rù ba ni, ó dáyà fo ni, ó sì lágbára gidigidi. Ó ní eyín irin títóbi; ó ń rùn, ó sì ń pa ohun alààyè tí ó ṣẹ́ kù jẹ, ó sì fi ẹsẹ̀ tẹ èyí tó kù mọ́lẹ̀. Ó yàtọ̀ sí gbogbo àwọn ẹranko ti ìṣáájú, ó sì ní ìwo mẹ́wàá.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 7

Wo Dáníẹ́lì 7:7 ni o tọ