Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 7:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lẹ́yìn ìgbà náà, mo tún rí ẹranko kẹta ó rí bí àmọ̀tẹ́kùn. Ẹranko náà ní ìyẹ́ bí i ti ẹyẹ ní ẹ̀yìn, ó sì ní orí mẹ́rin, a sì fún un ní agbára láti ṣe ìjọba.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 7

Wo Dáníẹ́lì 7:6 ni o tọ