Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 7:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mo sì tún rí ẹranko kejì, ó rí bí irú ẹranko ńlá kan tí ó ń gbé ilẹ̀ òtútù; bíárì. Ó gbé ara sókè ní apá kan, ó sì ní egungun ìhà mẹ́ta láàrin ẹ̀yìn in rẹ̀, wọ́n sì sọ fún un pé, ‘Dìde kí o sì jẹ ẹran tó pọ̀!’

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 7

Wo Dáníẹ́lì 7:5 ni o tọ