Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 7:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹranko kìn-ín-ní dàbí i kìnnìún, ó sì ní ìyẹ́-apá a idì: mo sì wò títí a fi fa ìyẹ́-apá rẹ̀ naa tu, a sì gbé e sókè kúrò ní ilẹ̀, a mú kí ó fi ẹsẹ̀ dúró bí ènìyàn, a sì fi àyà ènìyàn fún un.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 7

Wo Dáníẹ́lì 7:4 ni o tọ