Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 4:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àkókò kan náà, iyè mi padà, ọlá àti ògo dídán mi padà tọ̀ mí wá fún ògo ìjọba mi. Àwọn ìgbìmọ̀ àti àwọn ọlọ́lá mi, wá mi rí, wọ́n sì dá mi padà sórí ìjọba mi, mo sì di alágbára ju ti ìṣáájú lọ.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:36 ni o tọ