Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 4:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn ènìyàn ayéni a kà sí asán.Ó ń ṣe bí ó ti wù ú,pẹ̀lú àwọn ogun ọ̀run,àti gbogbo àwọn ènìyàn ayétí kò sì sí ẹnì kankan tí ó lè dí i lọ́wọ́tàbí sọ fún un wí pé: “Kí ni ìwọ ń ṣe?”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:35 ni o tọ