Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 4:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí, èmi, Nebukadinéṣárì fi ọpẹ́, mo sì gbé Ọlọ́run ga, mo sì fi ògo fún ọba ọ̀run, nítorí pé gbogbo nǹkan tí ó ṣe ló dára, gbogbo ọ̀nà rẹ̀ sì tọ́. Gbogbo àwọn tó sì ń rìn ní ìgbéraga ni ó le rẹ̀ sílẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:37 ni o tọ