Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 11:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò kọ lu àwọn ìlú olódi tí ó lágbára pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ òrìṣà àjèjì, yóò sì bu ọlá ńlá fún ẹni tí ó jẹ́wọ́ rẹ̀. Yóò mú wọn ṣe alákòóso lórí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn, yóò sì pín ilẹ̀ náà fún wọn gẹ́gẹ́ bí èrè.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11

Wo Dáníẹ́lì 11:39 ni o tọ