Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 11:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n dípò wọn, yóò bu ọlá fún òrìṣà àwọn ìlú olódi: òrìṣà tí àwọn baba rẹ̀ kò mọ̀ ni yóò bu ọlá fún pẹ̀lú wúrà àti fàdákà, pẹ̀lú òkúta iyebíye àti ẹ̀bùn tí ó lówó lórí.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11

Wo Dáníẹ́lì 11:38 ni o tọ