Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 11:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní àkókò ìgbà náà, ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ yóò dìde sí ọba Gúṣù. Àwọn ọlọ̀tẹ̀ nínú àwọn ènìyàn an rẹ̀ yóò ṣọ̀tẹ̀ ní ìmúṣẹ ìran náà, ṣùgbọ́n wọn kì yóò borí.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11

Wo Dáníẹ́lì 11:14 ni o tọ