Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì fa Jéhóíákímù ọba Júdà lé e lọ́wọ́, pẹ̀lú àwọn ohun èlò ilé Ọlọ́run. Àwọn nǹkan wọ̀nyí ni ó kó lọ sí ilé òrìṣà ní Bábílónì, sí inú ilé ìṣúra òrìṣà a rẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 1

Wo Dáníẹ́lì 1:2 ni o tọ