Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni ọba pàṣẹ fún Áṣípénásì, olórí àwọn ìwẹ̀fà ààfin rẹ̀ pé, kí ó mú nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tí wọ́n wá láti ìdílé ọba àti lára àwọn tí ó wá láti ilé ọlá.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 1

Wo Dáníẹ́lì 1:3 ni o tọ