Ní ọdún kẹta tí Jéhóíákímù jẹ ọba Júdà, Nebukadinéṣárì ọba Bábílónì wá sí Jérúsálẹ́mù, ó sì kọ lù ú pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun rẹ̀.