Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 8:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Yóò sì ṣe ní ọjọ́ náà,” ni Olúwa Ọlọ́run wí,“Èmi yóò mú òòrùn wọ̀ ní ọ̀sán,Èmi yóò mú kí ayé ṣókùnkùn ní ọ̀ṣán gangan.

Ka pipe ipin Ámósì 8

Wo Ámósì 8:9 ni o tọ