Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 8:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ǹjẹ́ ilẹ̀ náà kì yóò ha wárìrì fún èyí?Àwọn tí ń gbé inú rẹ̀ kì yóò ha sọ̀fọ̀?Gbogbo ilẹ̀ yóò ru sókè bí omi Náílì,yóò sì ru ú sókè pátapáta bí ìkún omia ó sì tì í jáde, a ó sì tẹ̀ ẹ́ rì gẹ́gẹ́ bí odò Éjíbítì.

Ka pipe ipin Ámósì 8

Wo Ámósì 8:8 ni o tọ