Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ámósì 8:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmí yóò yí àsè ẹ̀sìn yín padà sí ọ̀fọ̀,gbogbo orin yín ni èmi yóò sọ di ẹkún.Èmi yóò mú kí gbogbo yín wọ aṣọ ọ̀fọ̀,kí a sì fá orí i yín.Èmi yóò mú kí ìgbà náà rí bí ìṣọ̀fọ̀ fún ọmọkùnrinkan ṣoṣo tí a bí àti opin rẹ̀ bí ọjọ́ kíkorò.

Ka pipe ipin Ámósì 8

Wo Ámósì 8:10 ni o tọ