Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 59:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn ń pa ẹyín pamọ́lẹ̀wọn sì ń ta owú aláǹtakùn.Ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ ẹyin wọn yóò kú,àti nígbà tí a pa ọ̀kan, pamọ́lẹ̀ ni ó jáde.

Ka pipe ipin Àìsáyà 59

Wo Àìsáyà 59:5 ni o tọ