Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 59:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sí ẹni tí ó bèèrè fún ìdájọ́ òdodo;kò sí ẹni tí ó ro ẹjọ́ rẹ̀ pẹ̀lú òtítọ́.Wọ́n gbọ́kànlé àwíjàre aṣán àti ọ̀rọ̀ irọ́;wọ́n lóyún ìkà, wọn sì bí wàhálà

Ka pipe ipin Àìsáyà 59

Wo Àìsáyà 59:4 ni o tọ