Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 49:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun wí pé:“Ó jẹ́ ohun kékeré fún ọ láti jẹ́ ìránṣẹ́ miláti mú ẹ̀yà Jákọ́bù padà bọ̀ sípòàti láti mú àwọn ti Ísírẹ́lì tí mo ti pamọ́.Èmi yóò sì fi ọ́ ṣe ìmọ́lẹ̀ fún àwọn aláìkọlà,kí ìwọ kí ó lè mú ìgbàlà mi wásí òpin ilẹ̀ ayé.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 49

Wo Àìsáyà 49:6 ni o tọ