Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 49:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun tí Olúwa wí nìyìíOlùdáǹdè àti Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì—sí ẹni náà tí a gàn tí a sì kóríralọ́wọ́ àwọn orílẹ̀ èdè,sí ìránṣẹ́ àwọn aláṣẹ:“Àwọn ọba yóò rí ọ wọn yóò sì dìde sókè,àwọn ọmọ ọba yóò ríi wọn yóò sì wólẹ̀,nítorí Olúwa ẹni tí í ṣe olótìítọ́,Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì tí ó ti yàn ọ́.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 49

Wo Àìsáyà 49:7 ni o tọ