Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 49:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsìn yìí Olúwa wí péẹni tí ó mọ̀ mí láti inú wá láti jẹ́ ìránṣẹ́ rẹ̀láti mú Jákọ́bù padà tọ̀ mí wáàti láti kó Ísírẹ́lì jọ sọ́dọ̀ ara rẹ̀,nítorí pé a bọ̀wọ̀ fún mi ní ojú OlúwaỌlọ́run mi sì ti jẹ́ agbára mi

Ka pipe ipin Àìsáyà 49

Wo Àìsáyà 49:5 ni o tọ