Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 49:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Tẹ́tí sí mi, ẹ̀yin erékùṣù:gbọ́ èyí, ẹ̀yin orílẹ̀ èdè jínjìn-nà réré:kí a tó bí mi Olúwa ti pè mí;láti ìgbà bíbí mi ni ó ti dá orúkọ mi.

2. Ó ṣe ẹnu mi bí idà tí a pọ́n,ní abẹ́ òjìji ọwọ́ rẹ̀ ni ó ti pamí mọ́:ó ṣe mí ní ọfà tí a ti dán,ó sì fi mí pamọ́ sínú àpó rẹ̀.

3. Ó sọ fún mi pé, “Ìránṣẹ́ mi ni ìwọ í ṣe,Ísírẹ́lì nínú ẹni tí n ó ti fi ògo mi hàn.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 49