Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 49:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ṣe ẹnu mi bí idà tí a pọ́n,ní abẹ́ òjìji ọwọ́ rẹ̀ ni ó ti pamí mọ́:ó ṣe mí ní ọfà tí a ti dán,ó sì fi mí pamọ́ sínú àpó rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 49

Wo Àìsáyà 49:2 ni o tọ