Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 49:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tẹ́tí sí mi, ẹ̀yin erékùṣù:gbọ́ èyí, ẹ̀yin orílẹ̀ èdè jínjìn-nà réré:kí a tó bí mi Olúwa ti pè mí;láti ìgbà bíbí mi ni ó ti dá orúkọ mi.

Ka pipe ipin Àìsáyà 49

Wo Àìsáyà 49:1 ni o tọ