Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 49:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n èmi ṣọ pé, “Mo ti ṣe wàhálà lórí asán;mo ti lo gbogbo ipá mi lórí asán àti ìmúlẹ̀ mófo.Síbẹ̀ síbẹ̀ ohun tí ó tọ́ sími sì wà lọ́wọ́ Olúwa,èrè mi sì ń bẹ pẹ̀lú Ọlọ́run mi.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 49

Wo Àìsáyà 49:4 ni o tọ