Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 45:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí èyí ni ohun tí Olúwa wí—ẹni tí ó dá àwọn ọ̀run,Òun ni Ọlọ́run;ẹni tí ó mọ tí ó sì dá ayé,Òun ló ṣe é;Òun kò dá a láti wà lófo,ṣùgbọ́n ó ṣe é kí a lè máa gbé ibẹ̀—Òun wí pé:“Èmi ni Olúwa,kò sì sí ẹlòmìíràn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 45

Wo Àìsáyà 45:18 ni o tọ