Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 45:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Ísírẹ́lì ni a ó gbàlà láti ọwọ́ OlúwaPẹ̀lú ìgbàlà ayérayé;a kì yóò kàn yín lábùkù tàbí kí a dójú tì yín,títí ayé àìnípẹ̀kun.

Ka pipe ipin Àìsáyà 45

Wo Àìsáyà 45:17 ni o tọ