Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 45:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kò sọ̀rọ̀ níbi tí ó farasin,láti ibìkan ní ilẹ̀ òkùnkùn;Èmi kò tí ì sọ fún àwọn ìran Jákọ́bù pé‘Ẹ wá mi lórí asán.’Èmi Olúwa sọ òtítọ́;Mo sì sọ èyí tí ó tọ̀nà.

Ka pipe ipin Àìsáyà 45

Wo Àìsáyà 45:19 ni o tọ