Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 35:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kì yóò sí kìnnìún níbẹ̀,tàbí kí ẹranko búburú kí ó dìde lóríi rẹ̀;a kì yóò rí wọn níbẹ̀.Ṣùgbọ́n àwọn ẹni ìràpadà nìkan ni yóò rìn níbẹ̀,

Ka pipe ipin Àìsáyà 35

Wo Àìsáyà 35:9 ni o tọ