Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 35:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àwọn ẹni ìràpadà Olúwa yóò padà wá.Wọn yóò wọ Ṣíhónì wá pẹ̀lú orin;ayọ̀ ayérayé ni yóò dé wọn ní orí.Ìdùnnú àti ayọ̀ ni yóò borí i wọn,ìkorò àti ìtìjú yóò sì sá kúrò lọ́dọ̀ wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 35

Wo Àìsáyà 35:10 ni o tọ