Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 35:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti opópónà kan yóò wà níbẹ̀:a ó sì máa pè é ní ọ̀nà Ìwà-Mímọ́.Àwọn aláìmọ́ kì yóò tọ ọ̀nà náà;yóò sì wà fún àwọn tí ń rìn ní ọ̀nà náààwọn ìkà búburú kì yóò gba ibẹ̀ kọjá.

Ka pipe ipin Àìsáyà 35

Wo Àìsáyà 35:8 ni o tọ