Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa, ẹni tí ó ra Ábúráhámù padà sọ sí ilé Jákọ́bù:“Ojú kì yóò ti Jákọ́bù mọ́;ojúu wọn kì yóò sì rẹ̀wẹ̀sì mọ́.