Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 29:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àwọn tí wọ́n fi ọ̀rọ̀ kan mú ẹnìkan di ẹlẹ́bi,ẹni tí ń dẹkùn mú olùgbèjà ní kóòtùtí ẹ fi ẹ̀rí èkè dun aláìṣẹ̀ ní ìdájọ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 29

Wo Àìsáyà 29:21 ni o tọ