Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 23:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àní pẹpẹ tí ó wà ní Bétélì ibi gíga tí Jéróbóámù ọmọ Nébátí dá. Tí ó ti fa Ísírẹ́lì láti ṣẹ̀—Àní pẹpẹ náà àti ibi gíga tí ó fọ́ túútúú. Ó jó àwọn ibi gíga, ó sì lọ̀ ọ́ sí ẹ̀tù, ó sì ṣun òpó Áṣérà pẹ̀lú.

Ka pipe ipin 2 Ọba 23

Wo 2 Ọba 23:15 ni o tọ