Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 23:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jòṣíàh fọ́ òkúta yíyà sọ́tọ̀, ó sì gé òpó Áṣérà lulẹ̀. Ó sì bo ẹ̀gbẹ̀gbẹ́ ẹ rẹ̀ pẹ̀lú egungun ènìyàn.

Ka pipe ipin 2 Ọba 23

Wo 2 Ọba 23:14 ni o tọ