Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 23:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba pẹ̀lú ba ohun mímọ́ àwọn ibi gíga jẹ́ tí ó wà ní ìhà ìlà oòrùn Jérúsálẹ́mù ní ìhà gúṣù ti òkè ìbàjẹ́—èyí tí Ṣólómónì ọba Ísírẹ́lì ti kọ́ fún Ásítórétì ọlọ́run ìríra àwọn ará Ṣídónì, fún Kémóṣì ọlọ́run ìríra àwọn ará Móábù àti fún Mólékì, ọlọ́run ìríra àwọn ènìyàn Ámónì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 23

Wo 2 Ọba 23:13 ni o tọ