Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 23:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wó o palẹ̀ pẹpẹ tí àwọn ọba Júdà ti wọ́n gbé dúró ní ori òrùlé lẹ́bá yàrá òkè ti Áhásì pẹ̀lú àwọn pẹpẹ tí Mánásè ti kọ́ nínú ilé ẹjọ́ méjèèjì sí ilé Olúwa. Ó sí wọn kúrò níbẹ̀, ó fọ́ wọn sí wẹ́wẹ́. Ó sì da ekuru wọn sínú pẹ̀tẹ́lẹ̀ Kídírónì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 23

Wo 2 Ọba 23:12 ni o tọ