Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 23:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì kúrò láti ẹnu ọ̀nà àbáwọlé sí ilé Olúwa, àwọn ẹṣin tí àwọn ọba Júdà ti yà sọ́tọ̀ sí oòrùn náà. Wọ́n wà nínú ilé ẹjọ́ lẹ́bàá yàrá oníṣẹ́ tí orúkọ rẹ̀ a máa jẹ́ Nátanì-Mélékì. Jòṣíáyà sì ṣun àwọn kẹ̀kẹ́ tí a yà sọ́tọ̀ fún oòrùn.

Ka pipe ipin 2 Ọba 23

Wo 2 Ọba 23:11 ni o tọ