Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àádọ́ta àwọn ọkùnrin ọmọ wòlíì sì lọ láti lọ dúró ní ọ̀nà jínjìn, wọ́n sì kọ ojú da ibi tí Èlíjà àti Èlíṣà ti dúró ní Jọ́dánì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 2

Wo 2 Ọba 2:7 ni o tọ