Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà Èlíjà wí fún un pé, “Dúró níbí; Olúwa rán mi lọ sí Jọ́dánì.”Ó sì dá a lóhùn pé, “Gẹ́gẹ́ bí ó ti jẹ́ wí pé, Olúwa yè àti gẹ́gẹ́ bí o ti yè, èmi kò ní fi ọ́ sílẹ̀.” Bẹ́ẹ̀ ni àwọn méjèèjì sì jọ ń lọ.

Ka pipe ipin 2 Ọba 2

Wo 2 Ọba 2:6 ni o tọ