Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èlíjà sì mú agbádá ó sì ká a sókè ó sì lu omi náà pẹ̀lú rẹ̀. Omi náà sì pín sí ọ̀tún àti sí òsì, àwọn méjèèjì sì rékọjá lórí ilẹ̀ gbígbẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 2

Wo 2 Ọba 2:8 ni o tọ