Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 18:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Má ṣe tẹ́tí sí Héṣékíáyà. Èyí ni ohun tí ọba Ásíríà sọ: ‘Ṣe àlàáfíà pẹ̀lú mi kí o sì jáde wá sí ọ̀dọ̀ sí mi.’ Nígbà náà olúkúlùkù yín yóò jẹun láti inú àjàrà rẹ̀ àti igi ọ̀pọ̀tọ́, yóò sì mumi láti inú àmù rẹ̀,

Ka pipe ipin 2 Ọba 18

Wo 2 Ọba 18:31 ni o tọ