Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 18:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Títí tí èmi yóò fi wá mú ọ lọ sí ilé gẹ́gẹ́ bí i tìrẹ, ilẹ̀ ọkà àti ọtí wáìnì, ilẹ̀ ouńjẹ àti ọgbà àjàrà, ilẹ̀ òróró ólífì àti ti ilẹ̀ oyin; yàn ìye má sì ṣe yàn ikú!“Kí ẹ má ṣe gbọ́ tí Heṣekáyà, nítorí ó ń tàn yín tí ó ba tí wí pé, ‘Olúwa yóò gbà wá?’

Ka pipe ipin 2 Ọba 18

Wo 2 Ọba 18:32 ni o tọ