Má se jẹ́ kí Héṣékíáyà tì ọ́ láti gbàgbọ́ nínú Olúwa nípa sísọ pé, ‘Olúwa yóò gbà wá nítòótọ́; ìlú yìí ni wọn kò ní fi lé ọba ìlú Ásíríà lọ́wọ́.’