Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 17:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ní ọdún kejìlá ọba Áhásì ará Júdà, Hóséà ọmọ Élà jẹ ọba Ísírẹ́lì ní Ṣamáríà, ó sì jẹ fún ọdún mẹsàn án.

2. Ó sì ṣe búburú ní ojú Olúwa, ṣùgbọ́n kì í ṣe bí i ti ọba Ísírẹ́lì ẹni tí ó ti wà ṣáájú rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 17