Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 17:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọdún kejìlá ọba Áhásì ará Júdà, Hóséà ọmọ Élà jẹ ọba Ísírẹ́lì ní Ṣamáríà, ó sì jẹ fún ọdún mẹsàn án.

Ka pipe ipin 2 Ọba 17

Wo 2 Ọba 17:1 ni o tọ