Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 17:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣálámánesérì ọba Áṣíríà wá sókè láti mú Hóséà, ẹni tí ó ti jẹ fún Ṣálámánésérì ó sì ti san owó òde fún un.

Ka pipe ipin 2 Ọba 17

Wo 2 Ọba 17:3 ni o tọ