Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 5:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn afọ̀npè àti àwọn ọ̀kọrin pa ohùn wọn pọ̀ sí ọ̀kan soso, láti fi ìyìn àti ọpẹ́ fun Olúwa. Wọ́n fi ìpè, kíḿbálì àti àwọn ohun èlò orin mìíràn mọ́ ọn, wọ́n gbé ohùn wọn sokè láti fi yin Olúwa, wọ́n ń kọrin pé:“Ó dára;ìfẹ́ rẹ̀ wà títí láéláé.”Nígbà náà ni ìkùku ojú ọ̀run kún inú tẹ́ḿpìlì Olúwa,

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 5

Wo 2 Kíróníkà 5:13 ni o tọ